MV Maersk Andaman


MV Maersk Andaman (tẹ́lẹ̀tẹ́lè Maersk Alabama) jẹ́ ọkọ̀ ojú omi ẹlẹ́rù ti Maersk Line Limited tí ó wà ní ìmú ṣiṣẹ́ Waterman Steamship Corporation.[1] Ó ní àwọ̀ búlu tí ó fẹ́ mọ́ díẹ̀ pẹ̀lú ìrísí bi ti ọkọ̀  Maersk tókù láì wo tí àsíá ìforúkọsílẹ̀ wọn. Àwọn ajalèlókun jáagbà lẹgbẹ́ Somalia ní ọdún 2009, wọ́ sí mú àwọn atukọ̀ ẹ lati gba owó ìdásilẹ̀. Ìgbìyànjú mẹrin ọ̀tọ̀ọ̀tò lati já ọkọ̀ náà gbà jásí pàbó lẹ́yìn ọdún náà ní ọdún 2010 àti 2011.[2]

  1. "High Drama, High Stakes, High Seas – The Maersk Alabama Pirate Attack". SeaFever. April 8, 2009. 
  2. Cowell, Alan (November 18, 2009). "Pirates Attack Maersk Alabama Again". The New York Times. http://www.nytimes.com/2009/11/19/world/africa/19pirates.html. Retrieved November 18, 2009. 

From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Tubidy